The definition of health has evolved over time. |
Iyipada ti deba Itumo ilera |
In keeping with the biomedical perspective, early definitions of health focused on the theme of the body's ability to function; health was seen as a state of normal function that could be disrupted from time to time by disease. |
Ni ibamu pelu iwoye iwosan, ipile itumo ilera da lori bi ago ara n se sise, a si ri ilera gege bi ipo ise deede ti aisan le se idiwo fun ni igba de igba |
An example of such a definition of health is: "a state characterized by anatomic, physiologic, and psychological integrity; ability to perform personally valued family, work, and community roles; ability to deal with physical, biologic, psychological, and social stress". |
Apeere itumo ilera ni: "ipo ti o ni se pelu ise deede ago ara ni orisirisi ona; ipa lati se ojuse ti omuna doko ninu ebi, ise ati laarin agbegbe; ipa lati koju orisirisi wahala". |
Then, in 1948, in a radical departure from previous definitions, the World Health Organization (WHO) proposed a definition that aimed higher, linking health to well-being, in terms of "physical, mental, and social well-being, and not merely the absence of disease and infirmity". |
Ni odun 1948, iyipada ako otun si itumo tateyinwa waye, nigba ti ajo to n mojuto oro ilera ni agbaye ti a n pe ni World Health Organization (WHO) gbero itumo ti o nipon, ti o tokasi ibasepo ilera pelu igbe aye to dara, ti o ni se pelu ilera ti ara, opolo ati igbesi aye lawujo, ti ko da lori ai si ninu aisan tabi ailera nikan |
Although this definition was welcomed by some as being innovative, it was also criticized as being vague, excessively broad, and was not construed as measurable. |
Bo ti le je wi pe itumo yi je atewo gba gegebi eyi ti o mu ogbon akotun wa, kudie kudie nipa wipe ko soju abeniko daradara to, yo si soro lati gbe odiwon le na tun jeyo |
For a long time it was set aside as an impractical ideal and most discussions of health returned to the practicality of the biomedical model. |
Fun igba pipe, itumo yo ko je atewogba, ti pupo ninu awon ijiroro lori ilera si da lori ise amulo awose titi iwosan |
Just as there was a shift from viewing disease as a state to thinking of it as a process, the same shift happened in definitions of health. |
Gege bi ayipada se de ba riri aisan gege bi ipo si ilana, bakan na ni o se ri fun itumo ilera |
Again, the WHO played a leading role when it fostered the development of the health promotion movement in the 1980s. |
Siwaju si, ajo WHO je asiwaju ninu ifimule igbelaruge oro ilera ni odun 1980s |
This brought in a new conception of health, not as a state, but in dynamic terms of resiliency, in other words, as "a resource for living". |
E yi se okunfa itumo otun fun ilera, wipe ilera ki se ipo, sugbon nipa ti ifarada, ti a le pe gege bi" ohun elo fun igbe aye" |
The 1984 WHO revised definition of health defined it as "the extent to which an individual or group is able to realize aspirations and satisfy needs, and to change or cope with the environment. Health is a resource for everyday life, not the objective of living; it is a positive concept, emphasizing social and personal resources, as well as physical capacities". |
Itumo Ilera ti odun 1984 ti ajo WHO fi lele, o se apejuwe wipe ilera ni se pelu "iwon ti eniyan tabi ajo fi le ri wipe igbero ati ohun ti won nilo di imuse, ati lati mu ayipada tabi bawa pelu ayika. Ilere je ohun elo fun igbe aye ojoojumo, lai se idi ti a fi n gbe ile aye; o je asamo daradara, ti o fi oro ara eni ati ibasepo ti awujo rinle, si be si, agbara ti ara |
Thus, health referred to the ability to maintain homeostasis and recover from insults. |
Nitorina, ilera ni se pelu agbara lati samojuto idurosinsin ago ara ati la ti se atunse ati imubosipo fun idaru si idurosinsin yi |
Mental, intellectual, emotional, and social health referred to a person's ability to handle stress, to acquire skills, to maintain relationships, all of which form resources for resiliency and independent living |
Ilera ti opolo, ogbon ori, edun ara ati ibasepo lawujo ni se pelu agbara lati le bojuto wahala, nini imo, sise amojuto ibasepo, gbogbo re si je ohun elo fun ifarada ati igbe aye ominira |