Human rights or civil liberties form a crucial part of a country's constitution and govern the rights of the individual against the state. |
Awọn ẹtọ eniyan tabi awọn ominira ilu jẹ ọkan pataki ninu ofin orilẹ-ede kan ati iṣ'akoso awọn ẹtọ ti ẹni kọọkan si ilu.
|
Most jurisdictions, like the United States and France, have a codified constitution, with a bill of rights. |
Pupọ awọn sakani ijọba, bii Amẹrika ati Ilu Faranse, ni ofin t’ẹtọ, pẹlu iwe-aṣẹ awọn ẹtọ kan. |
A recent example is the Charter of Fundamental Rights of the European Union which was intended to be included in the Treaty establishing a Constitution for Europe, that failed to be ratified. |
Apẹẹrẹ ti o ṣẹṣẹ jẹ yọ ni Iwe-aṣẹ ti Awọn ẹtọ Pataki ti igbimo European Union eyiti o pinnu lati wa ninu adehun ti o ṣeto ilana-ofin fun Yuroopu, ti o kuna lati fọwọsi.
|
Perhaps the most important example is the Universal Declaration of Human Rights under the UN Charter. |
Ati paapaa apẹẹrẹ ti o ṣe pataki julọ ni Ikede Kariaye ti Awọn Eto Eda Eniyan labẹ UN Charter. |
These are intended to ensure basic political, social and economic standards that a nation state, or intergovernmental body is obliged to provide to its citizens but many do include its governments. |
Iwọnyi ni ipinnu lati rii daju pe awọn iṣedede iṣelu, ti awujọ ati eto-ọrọ ti ijọba orilẹ-ede kan, tabi ẹgbẹ alaṣẹ ijọba jẹ ọranyan lati pese fun awọn ara ilu ṣugbọn ọpọlọpọ ni pẹlu awọn ijọba rẹ.
|
Some countries like the United Kingdom have no entrenched document setting out fundamental rights; in those jurisdictions the constitution is composed of statute, case law and convention. |
Diẹ ninu awọn orilẹ-ede bii Ijọba United Kingdom ko ni iwe gbigbi ti o ṣeto awọn ẹtọ ipilẹ; ni awọn ijọba wọnyẹn ofin t’olofin jẹ, ti ofin ati apejọ.
|
A case named Entick v. Carrington is a constitutional principle deriving from the common law. |
Ẹjọ kan ti a npè ni Entick v. Carrington jẹ opo t’olofin ti o ngba lati ofin to wọpọ.
|
John Entick's house was searched and ransacked by Sherriff Carrington. |
Ile John Entick ni Sherriff Carrington gbon yebeyebe. |
Carrington argued that a warrant from a Government minister, the Earl of Halifax was valid authority, even though there was no statutory provision or court order for it. |
Carrington jiyan pe iwe aṣẹ lati ọdọ Minisita ijọba kan, Earl of Halifax jẹ aṣẹ to wulo, botilẹjẹpe ko si ipese ofin tabi aṣẹ ile-ẹjọ fun-un.
|
The court, led by Lord Camden stated that, |
Kootu naa, ti Oluwa Camden dari nipasẹ rẹ ṣalaye pe,
|
"The great end, for which men entered into society, was to secure their property. That right is preserved sacred and incommunicable in all instances, where it has not been taken away or abridged by some public law for the good of the whole. By the laws of England, every invasion of private property, be it ever so minute, is a trespass... If no excuse can be found or produced, the silence of the books is an authority against the defendant, and the plaintiff must have judgment." |
"Ipari nla, fun eyiti awọn ọkunrin ti wọ inu awujọ, ni lati ni aabo ohun-ini wọn. A tọju ẹtọ yẹn ni mimọ ati wipe koni abuja kankan ni gbogbo ayekaaye, nibiti ofin gbogbo gbo ko ti mu kuro tabi din ku fun rere gbogbo eniyan. Awọn ofin ti England, gbogbo igbogun ti ohun-ini aladani, bo ti le wu ko kere mo, jẹ ese labe ofin ... Ti ko ba si ikewo tabi gbejade, idakẹjẹ ti awọn iwe jẹ aṣẹ kan si olujejọ, ati pe olufisun naa gbọdọ ni idajọ . "
|